₦aijaPeeps(Create Topic) / Mobile Games / Videos / Foriegn Musics / Naija Musics / Gospel Musics / Upload Songs Welcome, Guest: Welcome, Guest: Join Naijapeeps / LOGIN! / Trending / Recent / Mobile Review (Spec) Stats:434 members, 439 topics. Date: Sun, 10 November 2024 at 6:14 am |
Anu Ni Mo Fe Akintunde Oladipuponaijapeeps / Naijapeeps / General / Music Lyrics / Anu Ni Mo Fe Akintunde Oladipupo (694 Views) Anu Ni Mo Fe Akintunde Oladipupofemtanyl – WEIGHTLESS! Lyrics / Bonnie McKee – Jenny’s Got A Boyfriend Lyrics / Maya Hawke – Hang In There Lyrics / (2) (3) (4) |
Anu Ni Mo Fe Akintunde Oladipupo by prayertitus: 6:57am March 31, 2024 |
Ifaara(Prelude): Olodu omo are. Ipa mi pin Jesu fanu gbami ooo(x2) Larin opo ijo eniyan fanu gbami ooo.
Alanu alai lenikan (jesu)×2 Eni nla Isreali, Oke rabata to kan satani satani laya, Oso gboruko Jesu jinijini bo ooo, Aje gboruko Jesu owa riri ooo, Olorun awon eni mimo to moye irawo, Oloju ariran, Wolewole to nwonu opolo, Oba ni rinrin ajo mafilesile, Oba ni lalejo wan tonile maje, Oba ni rinrin ajo mafile lowo, Oni gangan itura, mimo(x7), Owo kenbe rebi ja bi eni lo sere. Lead: Ipa mi pin Jesu fanu gbami ooo(x2) Response: Larin opo ijo eniyan fanu gbami ooo. Lead & Response: Anu mo nfe, anu lolese (x2). Ile pepe yi ti su mi oo, Ile pepe yi ti su mi oo, Oluwa, fanu gbami,baba alanu.
Vocal 1: Anu re O’luwa lawa ntoro, Ro ojo re lewa, Eye tinfo atera to nrin le, Nri won lopolopo. Response: Anu (×2) Anu re baba wa orun la wa ntoro, Eye tin fo atera to nrin le, Nri won lopolopo. Vocal 2: Orun losan nipa asere ni, Atosupa loru, Igba ojo ati gba ikore, Lowo re ni won wa. Response: Anu (×2) Anu re baba wa orun la wa ntoro, Nye tin fo atera to nrin le, nri won lopolopo. All: Anu mo nfe, anu lolese (x2). Ile pepe yi ti su mi oo, Ile pepe yi ti su mi oo, Oluwa, fanu gbami,baba alanu. Lead: Fanu fami dide ooo, fanu fami dide baba. Respons: Ko ma ma peju (x2) fanu fami dide o. Lead: Fanu fami dide o, fanu fami dide baba. Lead: Alanu sanu mi o, alanu saanu mi baba. Lead: Jesu saanu mi o, alanu saanu mi replete. Lead: Baba saanu mi o, Jesu saanu mi repete. Lead: Ka’yemi tan mole o, ka’yemi tan mole re baba. Lead: Ki’semi fo’go re han, Ki’semi fo’go re han baba. Lead: Kin mase subu lona iye, Ka’ye mase si o mi baba. Lead: Alanu saanu mi o, ka’ye ma se si o mi baba. comment |
Related Posts» Bonnie McKee – Jenny’s Got A Boyfriend Lyrics [6:57am March 31, 2024] » Liana Flores – I wish for the rain Lyrics [6:57am March 31, 2024] » Moses Bliss ft SPOTLITE Stars - You are Great Lyrics [6:57am March 31, 2024] » Lyrics: Innocent Nwokenta – What A Friend [6:57am March 31, 2024] » Emmanuel Iren ft Nathaniel Bassey - AGALLIAO Lyrics [6:57am March 31, 2024] » Maya Hawke – Hang In There Lyrics [6:57am March 31, 2024] » femtanyl – WEIGHTLESS! Lyrics [6:57am March 31, 2024] » Cellarr – Let Go Lyrics [6:57am March 31, 2024] » Gloria Peter - Olore Ofe (Gracious God) Lyrics [6:57am March 31, 2024] » Nga Yesu lyrics by Waade [6:57am March 31, 2024] |
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) education (1) romance computers phones sports fashion health religion celebs tv-movies music & lyrics literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Naijapeeps.wapkiz.com is a great mobile download forum 2020 which comes with a very simple and interface, you can download mobile games java apk zip, mp4, mp3, audio, Music Lyrics and TV series all for free. |