Ebe Lyrics by Sola Allyson

naijapeeps / Naijapeeps / General / Music Lyrics / Ebe Lyrics by Sola Allyson (3166 Views)


Download Music: Uchechi – Faithful Father mp3 / SPOTLIGHT Lyrics – Moses Bliss / Chidinma Jehovah Overdo Lyrics + Video mp4 download /
(2) (3) (4)

(Go Down)

Ebe Lyrics by Sola Allyson by prayertitus Admin.: 5:14pm July 17, 2020

Sola Allyson - Ebe Lyrics

Lord, I’ve come to seek Your face

Let Your grace and

Your mercy come upon me, Lord


Oh Lord, I call upon Your name

Let the rain of Your mercy

Pour upon me, Lord


O oo Oluwa, mo wa sibi ite

Je ki oore ofe ati aanu Re,

Oluwa Ko ba le mi lori

Oluwa, mo ke p’Oruko Re

Je ki ojo aanu Re o, Baba

Ko ro s’ori iseda mi


Baba oo ooo, eyi l’ebe o

Baba oo ooo, eyi l’ebe o

(Baba Alaanu, Olugbebe, gbo ebe mi Oluwa o)

Baba oo ooo, eyi l’ebe o

(Aye mi ko bu ola fun O ni mo n beere)

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)


Ona mi to wo,

ko di tito ninu ife Re Oluwa o,

Eyi ni ebe mi o


Gba mi lowo asise, Oluwa o

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka,

Gba mi lowo ogun irandiran,

Oluwa gba mi oo Baba,

Iwo ni mo gbeke mi le o,

Eni to ni emi mi

Oluwa too ba to mu awon afoju san,

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Oba to ji oku omo Jairu dide,

Oku Lasaru,

ojo merin, o ti n ra, o ti n run,

Iwo lo ji i dide o, Oluwa saanu mi


Jesu, omo Dafidi, gbo adua mi,

Oluwa

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Baba oooo, Oore ofe Re ni mo beere,

aye o see gbe laisi oore ofe Re, Oluwa o

Mo fi oore ofe Re ra aye gbe, Oluwa

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)


Atupa imo mi ko ma se ku lailai

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Iwo ni opo fitila to n tan fun emi mi Oluwa ooo

Oro Re wipe bi mo beere, ma a ri gba,

mo n beere ki n ri gba

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Bi mo ba kan ‘lekun,

ilekun a si, ilekun ko si,

a si ti ko wipe,

bi mo ba wa kiri, ma a ri,

mo n wa kiri, ki n ri o,

ki n ni ere to po, Oluwa o


Baba Alaanu ooo

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Ohun gbogbo to wa ninu iseda n gbimo aanu

si ayanmo mi, won n sise

iranwo lori ayanmo mi, Oluwa o


Ilekun si le, ilekun aanu si le, Oluwa

(Baba oo ooo, eyi l’ebe o)

Aanu ro sori mi, o ro sori mi bee,

Olugbebe gbo ebe mi o


Oh Lord I’ve come to seek Your face

Let Your grace and

Your mercy come upon me, Lord

Oh Lord, I call upon Your name

Let the rain of Your mercy

pour upon me, Lord

Oluwa, mo wa sibi ite

Je ki aanu ati oore ofe Re

Ko ba le mi lori

Oluwa, mo ke p’Oruko Re

Je ki ojo aanu Re

Ko ro s’ori iseda mi


Baba oo ooo, eyi l’ebe o

Baba oo ooo, eyi l’ebe o


I am a Vibrant Internet Stunner!!!, Simple but Complex

0 comment Be the first person to comment! (Reply)

Add Comment

Your Name:

Comment:

Smilies List

Related Posts